All releases uploaded on the CiDAR Africa platform automatically falls under our standard distribution license from the moment of upload. For more details, please see our contract form page and contract terms.
Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
Ọrọ mi d′akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
Ẹni j′alangba n tutu, a ko warapa
Oh-ah, oh-ah-ah-ah
Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah
Oh-wa, oh, wa-wa-wa
(Nobody's perfect)
Yea, ki'ku ma-ma pa awọn to gbe mi s′ori bi gele
Ki ibaunjẹ jina siwa rere, ay, tefe-tefe
Ki′ku maa p'ọta mi, ko le riran-wo
(O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)
Ki′ku maa p'ọta mi, ko le riran-wo
(Mo ṣi n m′ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one, motivation gan-an ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ (ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ ọ)
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o?
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
Yeah, as I dey find wetin I go chop, ooh-iy-iy
Make I no jam wetin go chop me
Oluwa lo gbe (yea-yea), lo gbe mi soke
Emi ko le ṣa i ṣọpẹ
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (yeah)
Yeah, o loju ọmọ to damọ
If I see say wahala don dey too much
Na to roll up a big fat one, motivation gan-an ti n pa′yan, wahala nikan kọ o

(Sunshine)